Enikeni toba si ngbadura pe nigeria maa daa tabi enikan lee tunse, iro lowa nidi e.. They didn't use prayer to build America, China, Uk, Germany, and so on.
Iyenipe olorun loniki tinubu ma fi ebi pawa tabi kiwon yi ibo tabi ki awon janduku koma le awon oludibo kuro ni pulling unit tabi ki awon to nkowoje kiwon won malo ni alafia, se olorun yin nife si ese ati rudurudu bi, Bibeli ti mo ka wipe, ti olododo ba nse ijoba gbogbo ilu yio ma yo.