Eogba Olorun gbo sir, enyan melo lori Owo fira cement nigbati wonta ni #100? Lasikoyi tiwon nta ni #15,000 se Awon enyan o kole mo? Eomo Olorun rara sir
Ki l'o de ti iru Baba onisokuso yi ko ri air crash t'o sele nitosi odo re ni Igbokoda Ondo State sugbon awon iran iro ni won nri si awon ti Olorun ti gbe ga si ipo ijoba ???
Baba o ye ki e ma gba adura fun Nigeria ni Se Atiku le fe ni abi Obi. Se unkan ti Shagari se da ni .E soro si yen.E je ki Precedent Tinubu se 8 years then you can talk.
Onisokuso ni Baba yi. Iro nla l'e npa shebi won so wipe Tinubu ko ni di President Nigeria ati wipe t'o ba di President Nigeria oun a pada si ise Babalawo ati ise agbe sise. Gomina Adeleke ko ni se ewon lagbara Olorun ki Baba onisokuso yi ko ara re da sibi kan ti ko ba mo ohun t'o ye k'o so mo. Beeni o ntenu mo wipe Omo Oba Owo kan ni o maa pada je President dipo Tunubu !!!
Alore stop interview this baba about politics, interview him on other things, he doesn't understand it. Nigeria has never been easy. It's always be a third/developing nation