Baba yi nkan tan nbere ko lodahun nipa Gomina dapo Abiodun Sugbon Olorun abi gbogbo yin papo nitori Dapo ose dada fun odun mejo tolo bridge Epe road ni ijebu ode to se gan konitumo ati bebe lo
Gbogbo lafenwa, Ayetoro ltele so sunmo Ayobo, iya to nje awon ti o ngbe ibe lati bi 15 years ko kere tori aisi ona, ti ojo ba ro, ose meji awon eniyan o ni le gbe motor jade fun ose meji. Iro lo ma pa awon oloselu.