It is the duty of every reasonable Yoruba man and woman to contribute immensely to the rapid industrial and overall development of Ile Ife. Anything you do/say for or against Ile Ife will certainly come back to you and your community in manifolds. It is spiritual! A river that forgets its source shall surely run dry.
Ẹku eto o Baba asa, kosi ẹni to mọ tan. Ọrọ owurọ lọjọ ti ẹni ẹmu ni wọn fin mu ni liẹ ifẹ , bẹkọ ni o . Okodoro Ọrọ naa ni wipe "owurọ ọdun ọlọjọ ẹmu ni wọn mu ni ilẹ ifẹ" kise owurọ kutu ai o. Ase pupọ Ni idi eyi ẹ se atun se ni ibẹyẹn.
Well done baba Asa GOD bless more knowledge and wisdom strength oponu a mu ku meko eda ni pastor to soro yen a fi bi Dolores won ni ko le ma ba olori aye je